2 Kíróníkà 28:12 BMY

12 Lẹ́yìn náà, díẹ̀ nínú àwọn olórí ní Éfùráímù Ásáríyà ọmọ Jehóhánánì, Béríkià ọmọ Méṣílemóti, Jehísikíà ọmọ Ṣaílúmù, àti Ámásà ọmọ Hádíà, dìde sí àwọn tí o ti ogun náà bọ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 28

Wo 2 Kíróníkà 28:12 ni o tọ