2 Kíróníkà 28:19 BMY

19 Olúwa sì rẹ Júdà sílẹ̀ nítorí Áhásì ọba Ísírẹ́lì, nítorí ó sọ Júdà di aláìní ìrànlọ́wọ́, ó sì se ìrékọjá gidigidi sí Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 28

Wo 2 Kíróníkà 28:19 ni o tọ