2 Kíróníkà 28:25 BMY

25 Ní gbogbo ìlú Júdà ó sì kọ́ ibi gíga láti sun ẹbọ fún àwọn Ọlọ́run mìíràn. Kí ó sì mú Olúwa, Ọlọ́run àwọn Baba wọn bínú.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 28

Wo 2 Kíróníkà 28:25 ni o tọ