2 Kíróníkà 29:28 BMY

28 Gbogbo ìjọ ènìyàn náà sì wólẹ̀ sìn, àwọn akọrin kọrin, àwọn afọ̀npè sì fọn ìpè: gbogbo wọ̀nyí sì wà bẹ́ẹ̀ títí ẹbọ sísun náà fi parí tán.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 29

Wo 2 Kíróníkà 29:28 ni o tọ