2 Kíróníkà 29:32 BMY

32 Iye ẹbọ sísun, tí ìjọ ènìyàn mú wá, sì jẹ́ àádọ́rin akọ màlúù, àti ọgọ́rùnún àgbò, àti igba ọ̀dọ́-àgùntàn: gbogbo wọ̀nyí sì ni fún ẹbọ ṣíṣun sí Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 29

Wo 2 Kíróníkà 29:32 ni o tọ