2 Kíróníkà 29:7 BMY

7 Wọ́n sì tún ti ìlẹ̀kùn ìloro náà pẹ̀lú, wọ́n sì pa Fìtílà. Wọn kò sì sun tùràrí tàbí pèsè ẹbọ sísun si ibi mímọ́ si Ọlọ́run Ísirẹ́lì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 29

Wo 2 Kíróníkà 29:7 ni o tọ