2 Kíróníkà 3:7 BMY

7 Ó tẹ́ àjà ilé náà pẹ̀lú ìtí igi àti ìlẹ̀kùn ògiri àti àwọn ìlẹ̀kùn ilé Olúwa Pẹ̀lú wúrà, ó sì gbẹ́ àwòrán kérúbù sára ògiri.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 3

Wo 2 Kíróníkà 3:7 ni o tọ