2 Kíróníkà 30:12 BMY

12 Ní Júdà pẹ̀lú, ọwọ́ Ọlọ́run wá láti fún wọn ní ọkàn kan láti pa òfin ọba mọ́ àti tí àwọn ìjòyè, nípa ọ̀rọ̀ Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 30

Wo 2 Kíróníkà 30:12 ni o tọ