2 Kíróníkà 30:14 BMY

14 Wọ́n sì dìde, wọ́n sì kó gbogbo pẹpẹ tí ó wà ní Jérúsálẹ́mù lọ, àti gbogbo pẹpẹ tùràrí ni wọ́n kó lọ, wọ́n sì dà wọ́n sí odò Kídírónì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 30

Wo 2 Kíróníkà 30:14 ni o tọ