2 Kíróníkà 31:20 BMY

20 Èyí ni Heṣekáyà ṣe jákèjadò Júdà, ó sì ṣe ohun tí ó dára àti tí ó tọ́ àti ohun òtítọ́ níwájú Olúwa Ọlọ́run rẹ̀,

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 31

Wo 2 Kíróníkà 31:20 ni o tọ