2 Kíróníkà 31:8 BMY

8 Nígbà tí Heṣekáyà àti àwọn oníṣẹ́ rẹ̀ wá, tí wọ́n sì rí òkítì náà, wọ́n yin Olúwa, pẹ̀lú ìbùkún àwọn ènìyàn rẹ̀ Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 31

Wo 2 Kíróníkà 31:8 ni o tọ