2 Kíróníkà 32:30 BMY

30 Heṣekíà ni ó dí ojú ìṣúra apá òkè ti orísun Gíhónì. Ó sì gbe gba ìsàlẹ̀ sí ìhà ìwọ oòrùn ìlú ńlá ti Dáfídì. Ó ṣe àṣeyọrí sí rere nínu gbogbo ohun tí ó dáwọ́lé.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 32

Wo 2 Kíróníkà 32:30 ni o tọ