2 Kíróníkà 33:15 BMY

15 Ó pa gbogbo àwọn Ọlọ́run àjòjì run. Ó sì hú gbogbo àwọn ère kúrò nínú ilé Olúwa, pẹ̀lú gbogbo àwọn pẹpẹ tí ó ti kọ́ ní òkè ilé Olúwa àti ní Jérúsálẹ́mù; ó sì kó wọn jáde kúrò nínú ìlú.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 33

Wo 2 Kíróníkà 33:15 ni o tọ