2 Kíróníkà 33:18 BMY

18 Àwọn isẹ́ yòókù ti ìjọba Mánásè pẹ̀lú àdúrà rẹ̀ sí Ọlọ́run rẹ̀ àti àwọn ọ̀rọ̀ tí àwọn aríran sọ sí i wà nínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 33

Wo 2 Kíróníkà 33:18 ni o tọ