2 Kíróníkà 33:20 BMY

20 Mánásè sinmi pẹ̀lú àwọn bàbá rẹ̀, a sì sin ín sínú ààfin rẹ̀. Ámónì ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 33

Wo 2 Kíróníkà 33:20 ni o tọ