2 Kíróníkà 33:3 BMY

3 Ó tún kọ́ àwọn ibi gíga tí baba rẹ̀ Heṣekáyà ti fọ́ túútúú. Ó sì gbé àwọn pẹpẹ dìde fún àwọn Báálì ó sì ṣe àwọn òpó Áṣérà. Ó foríbalẹ̀ fún gbogbo àwọn ogun ọ̀run ó sì sìn wọ́n.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 33

Wo 2 Kíróníkà 33:3 ni o tọ