2 Kíróníkà 34:1 BMY

1 Jósíà sì jẹ́ ẹni ọdún mẹ́jọ nígbà tí ó jẹ ọba, ó sì dí ọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún mọ́kànlélọ́gbọ̀n (31).

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 34

Wo 2 Kíróníkà 34:1 ni o tọ