2 Kíróníkà 34:11 BMY

11 Wọ́n sì tún fi owó fún àwọn ọlọ́nà àti àwọn olùkọ́lé láti ra òkúta gbígbẹ́ àti ìtì igi fún ìsopọ̀ àti igi rírẹ́ fún ìkọ́lé tí ọba Júdà ti gbà láti tẹ́ ilé tí wọ́n ti bàjẹ́.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 34

Wo 2 Kíróníkà 34:11 ni o tọ