2 Kíróníkà 34:13 BMY

13 Wọ́n sì ní olórí àwọn aláàárù àti àwọn alábojútó gbogbo àwọn òṣìsẹ́ láti ibisẹ́ si ibisẹ́, díẹ̀ nínú àwọn ọmọ Léfì sì ní alákọ̀wé, olùtọ́jú àti olùsọ́nà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 34

Wo 2 Kíróníkà 34:13 ni o tọ