2 Kíróníkà 34:18 BMY

18 Nígbà náà Ṣáfánì akọ̀wé sì sọ fún ọba, “Hílíkíyà àlùfáà ti fún mi ní ìwé.” Ṣáfánì sì kà níwájú ọba.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 34

Wo 2 Kíróníkà 34:18 ni o tọ