2 Kíróníkà 34:32 BMY

32 Nígbà náà, ó sì mú kí gbogbo ènìyàn ní Jérúsálẹ́mù àti Bẹ́ńjámínì dúró nínú ẹ̀rí fún ara wọn, àwọn ènìyàn Jérúsálẹ́mù ṣe èyí gẹ́gẹ́ bi májẹ̀mú Ọlọ́run, Ọlọ́run Baba wọn.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 34

Wo 2 Kíróníkà 34:32 ni o tọ