2 Kíróníkà 34:7 BMY

7 Ó sì wó pẹpẹ àti ère òrìṣà lulẹ̀ àti àwọn ère yíyá àti àwọn òrìṣà, ó sì gùn ó sì ti ké gbogbo àwọn ère orí pẹpẹ lulẹ̀ ní gbogbo àyíká Ísírẹ́lì. Lẹ́yìn náà ó padà sí Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 34

Wo 2 Kíróníkà 34:7 ni o tọ