2 Kíróníkà 35:20 BMY

20 Lẹ́yìn gbogbo èyí nígbà tí Jósíà ti tún ilẹ̀ náà se tán, Nékò ọba Éjíbítì gòkè lọ láti bá Keríkemísì jà lórí odo Éúfírátè, Jósíà sì jáde lọ láti pàdé rẹ̀ ní ibi ìjà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 35

Wo 2 Kíróníkà 35:20 ni o tọ