2 Kíróníkà 5:2 BMY

2 Nígbà náà ni Sólómónì pe àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì jọ sí Jérúsálẹ́mù, gbogbo àwọn olórí ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan àti àwọn olóyè àwọn ìdílé Ísírẹ́lì, kí wọn kí ó gbé àpótí ẹ̀rí Májẹ̀mu Olúwa gòkè wá láti síónì ìlú Dáfídì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 5

Wo 2 Kíróníkà 5:2 ni o tọ