2 Kíróníkà 6:12 BMY

12 Nígbà naà ni Sólómónì dúró níwájú pẹpẹ Olúwa, ní iwájú gbogbo ìjọ ènìyàn Isírẹ́lì, ó sì tẹ́ ọwọ́ọ rẹ̀ méjèèjì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 6

Wo 2 Kíróníkà 6:12 ni o tọ