2 Kíróníkà 7:12 BMY

12 Olúwa sì farahàn ní òru ó sì wí pé:“Èmi ti gbọ́ àdúrà rẹ mo sì ti yàn ibííyí fún ara mi gẹ́gẹ́ bí ilé fún ẹbọ.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 7

Wo 2 Kíróníkà 7:12 ni o tọ