2 Kíróníkà 7:3 BMY

3 Nígbà tí gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì rí iná tí ó ń sọ̀kalẹ̀ àti ògo Olúwa lórí ilé Olúwa náà, wọ́n sì kúnlẹ̀ lórí eékún wọn pẹ̀lú ojú wọn dídàbolẹ̀, wọ́n sì sin Olúwa, wọ́n sì fi ìyìn fún Olúwa wí pé,“Nítorí tí ó dára;àánú rẹ̀ sì dúró títí láéláé.”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 7

Wo 2 Kíróníkà 7:3 ni o tọ