2 Kíróníkà 8:2 BMY

2 Sólómónì tún ìlú tí Hírámù ti fi fún un kọ́, ó sì kó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jọ níbẹ̀ kí wọn kí ó lè máa gbé nínú ibẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 8

Wo 2 Kíróníkà 8:2 ni o tọ