2 Kíróníkà 9:11 BMY

11 Ọba sì lo igi álígúmù náà láti fi ṣe àtẹ̀gùn fún ilé Olúwa àti fún ilé ọba àti láti fi ṣe dùùrù àti ohun ọ̀nà orin fún àwọn akọrin. Kò sì sí irú rẹ̀ tí a ti rírí ní ilẹ̀ Júdà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 9

Wo 2 Kíróníkà 9:11 ni o tọ