2 Kíróníkà 9:31 BMY

31 Sólómónì sì sùn pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀, a sì sin ín ní ìlú Dáfídì baba rẹ̀, Réhóbóámù, ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 9

Wo 2 Kíróníkà 9:31 ni o tọ