2 Kíróníkà 9:9 BMY

9 Nígbà náà ni ó sì fún ọba ní ọgọ́fà talẹ́ntì wúrà (120). Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iye tùràrí, àti òkúta iyebíye. Kò sì tíì sí irú tùràrí yí gẹ́gẹ́ bí èyí tí ayaba Ṣébà fifún ọba Sólómónì.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 9

Wo 2 Kíróníkà 9:9 ni o tọ