14 Bẹ́ẹ̀ ni Hébúrónì jẹ́ ti Kélẹ́bù ọmọ Jéfúnè ará Kánísì láti ìgbà náà, nítorí tí ó tẹ̀lé Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì tọkàntọkàn.
Ka pipe ipin Jóṣúà 14
Wo Jóṣúà 14:14 ni o tọ