Jóṣúà 14:15 BMY

15 (Hébúrónì a sì máa jẹ́ Kíríàtì Áríbà ní ẹ̀yìn Áríbà, èyí tí ó jẹ́ ènìyàn ńlá nínú àwọn ọmọ Ánákì.)Nígbà náà ni ilẹ̀ náà sinmi ogun.

Ka pipe ipin Jóṣúà 14

Wo Jóṣúà 14:15 ni o tọ