Jóṣúà 14:7 BMY

7 Mo jẹ́ ọmọ ogójì ọdún nígbà tí Mósè ìránṣẹ́ Olúwa rán mi láti Kádesi-Báníyà lọ rin ilẹ̀ náà wò. Mo sì mú ìròyìn wá fún un gẹ́gẹ́ bí o ti dá mi lójú,

Ka pipe ipin Jóṣúà 14

Wo Jóṣúà 14:7 ni o tọ