Jóṣúà 14:8 BMY

8 ṣùgbọ́n àwọn arákùnrin mi tí wọ́n bá mi lọ mú àyà àwọn ènìyàn já. Ṣùgbọ́n ní tèmi, èmi fi gbogbo ọkàn tẹ̀lé Olúwa Ọlọ́run mi.

Ka pipe ipin Jóṣúà 14

Wo Jóṣúà 14:8 ni o tọ