Jóṣúà 15:3 BMY

3 Ó sì lọ sí gúsù Sikopioni Pasi lọ títi dé Sínì àti sí iwájú ìhà gúsù Kadesi Báníyà. Nígbà náà ó sì tún kọjá Hésórónì lọ sí Ádárì, ó sì tún yípo yíká lọ sí Kákà.

Ka pipe ipin Jóṣúà 15

Wo Jóṣúà 15:3 ni o tọ