Jóṣúà 2:21 BMY

21 Ó dáhùn pé, “Ó dára bẹ́ẹ̀.” “Ẹ jẹ́ kí ó rí gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin tí ṣọ.” Ó sì rán wọn lọ, wọ́n sì lọ. Ó sì so okùn òdòdó náà sí ojú u-fèrèsé.

Ka pipe ipin Jóṣúà 2

Wo Jóṣúà 2:21 ni o tọ