Jóṣúà 2:22 BMY

22 Nígbà tí wọ́n kúrò, wọ́n sì lọ sí orí òkè, wọ́n sì dúró ní ibẹ̀ ní ọjọ́ mẹ́ta, títí àwọn alépa fi wá wọn ní gbogbo ọ̀nà wọ́n sì padà láìrí wọn.

Ka pipe ipin Jóṣúà 2

Wo Jóṣúà 2:22 ni o tọ