Jóṣúà 2:23 BMY

23 Nígbà náà ni àwọn ọkùnrin méjì náà padà. Wọ́n sì ṣọ̀kalẹ̀ láti orí òkè, wọ odò, wọ́n sì wá sí ọ̀dọ̀ Jóṣúà ọmọ Núnì; wọ́n sì sọ fún un gbogbo ohun tí ó ti sẹlẹ̀ sí wọn.

Ka pipe ipin Jóṣúà 2

Wo Jóṣúà 2:23 ni o tọ