Jóṣúà 2:3 BMY

3 Ọba Jẹ́ríkò sì ránṣẹ́ sí Ráhábù pé: “Mú àwọn ọkùnrin nì tí ó tọ̀ ọ́ wá, tí ó wọ inú ilé rẹ jáde wá, nítorí wọ́n wá láti yọ́ gbogbo ilẹ̀ yìí wò ni.”

Ka pipe ipin Jóṣúà 2

Wo Jóṣúà 2:3 ni o tọ