Jóṣúà 2:4 BMY

4 Ṣùgbọ́n obìnrin náà ti mú àwọn ọkùnrin méjì náà, o sì fi wọ́n pamọ́. Ó sì wí pé, “lóótọ́ ní àwọn ọkùnrin náà wá sí ọ̀dọ̀ mi, ṣùgbọ́n èmi kò mọ ibi tí wọ́n ti wá.

Ka pipe ipin Jóṣúà 2

Wo Jóṣúà 2:4 ni o tọ