Jóṣúà 24:2 BMY

2 Jóṣúà sì sọ fun gbogbo ènìyàn pé, “Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì, wí: ‘Nígbà kan rí àwọn baba ńlá yín Térà bàbá Ábúráhámù àti Náhórì ń gbé ní ìkọjá odò, wọ́n sì sin àwọn òrìṣà.

Ka pipe ipin Jóṣúà 24

Wo Jóṣúà 24:2 ni o tọ