Jóṣúà 24:33 BMY

33 Élíásérì ọmọ Árónì sì kú, wọ́n sì sin ín ní Gíbéà, tí a ti pín fún ọmọ rẹ̀ Fínéhásì ní òkè ilẹ̀ Éfúráímù.

Ka pipe ipin Jóṣúà 24

Wo Jóṣúà 24:33 ni o tọ