Onídájọ́ 1:1 BMY

1 Lẹ́yìn ikú Jóṣúà, ni orílẹ̀-èdè Ísírẹ́lì béèrè lọ́wọ́ Olúwa pé “Èwo nínú ẹ̀yà wa ni yóò kọ́kọ́ gòkè lọ bá àwọn ará Kénánì jagun fún wa?”

Ka pipe ipin Onídájọ́ 1

Wo Onídájọ́ 1:1 ni o tọ