Jóṣúà 24:9 BMY

9 Nígbà tí Bálákì ọmọ Sípórì, ọba Móábù, múra láti bá Ísírẹ́lì jà, ó ránṣẹ́ sí Bálámù ọmọ Béóríù láti fi yín bú.

Ka pipe ipin Jóṣúà 24

Wo Jóṣúà 24:9 ni o tọ