Jóṣúà 5:7 BMY

7 Bẹ́ẹ̀ ni ó gbé àwọn ọmọ wọn dìde dípò wọn, àwọn wọ̀nyí sì ni Jóṣúà kọ ní ilà. Wọ́n wà ní aláìkọlà nítorí a kò tíì kọ wọ́n ní ilà ní ojú ọ̀nà.

Ka pipe ipin Jóṣúà 5

Wo Jóṣúà 5:7 ni o tọ