Jóṣúà 5:8 BMY

8 Lẹ́yìn ìgbà tí gbogbo orílẹ̀ èdè náà kọ ilà tan, wọ́n dúró ní ibi tí wọ́n wà ní ibùdó títí ilà wọn fi jinná.

Ka pipe ipin Jóṣúà 5

Wo Jóṣúà 5:8 ni o tọ