Jóṣúà 5:9 BMY

9 Nígbà náà ní Olúwa wí fún Jóṣúà pé, “Ní òní ni mo yí ẹ̀gàn Éjíbítì kúrò ní orí yín.” Nítorí náà ni a ṣe ń pe orúkọ ibẹ̀ ní Gílígálì títí ó fi di òní yìí.

Ka pipe ipin Jóṣúà 5

Wo Jóṣúà 5:9 ni o tọ