Jóṣúà 6:11 BMY

11 Bẹ́ẹ̀ ni ó mú kí àpótí ẹ̀rí Olúwa yí ìlú náà ká, ó sì yí i ká lẹ́ẹ̀kan. Nígbà náà ni àwọn ènìyàn náà padà sí ibùdó wọ́n sì gbé ibẹ̀ fún alẹ́ náà.

Ka pipe ipin Jóṣúà 6

Wo Jóṣúà 6:11 ni o tọ