Jóṣúà 6:10 BMY

10 Ṣùgbọ́n Jóṣúà tí pàṣẹ fún àwọn ènìyàn pé, “Ẹ kò gbọdọ̀ kí-gbe ogun, ẹ kò gbọdọ̀ gbé ohùn yín sókè, ẹ má ṣe sọ ọ̀rọ̀ kan títí ọjọ́ tí èmi yóò sọ fún un yín pé kí ẹ hó. Nígbà náà ni ẹ̀yin yóò sì hó!”

Ka pipe ipin Jóṣúà 6

Wo Jóṣúà 6:10 ni o tọ